Adwenkyerɛ Nnetwerɛ

Ɛha na mekyerɛ m'adwene fa deɛ mepɛ biara ho.

Do you speak Afrikan? How to say "Uhuru!" and Ọbádélé

Continue reading
1293 Hits
0 Comments

Do you speak Afrikan? Àṣẹ Addendum and How to say "Abibifahodie!"

Continue reading
1053 Hits
0 Comments

Do you speak Afrikan? How to say "Àṣẹ!" by Dr. Obadele Kambon

Do you speak Afrikan? How to say "Àṣẹ!" by Dr. Obadele Kambon

Continue reading
1171 Hits
0 Comments

Ìyàtọ̀ l'áàrin Ìwà rere àti Ìwà-pẹ̀lẹ́

Ìyàtọ̀ l'áàrin Ìwà rere àti Ìwà-pẹ̀lẹ́

Àwọn Yorùbá máa ń pa á l'ówe pé, "Gbogbo nǹkan l'ó ní àsìkò tirẹ̀"

 

Òwe yìí ṣe pàtàkì fún ẹnikẹ́ni t'ó bá fẹ́ mọ bí àwa Adúláwọ̀ ṣe ń bójúwo ayé.

 

Ìwà pẹ̀lẹ́ l'ó ní àsìkò tirẹ̀

Ìwà jagunjagun l'ó sì tún l'ásìkò tirẹ̀

Tẹ̀mí l'ó ní àsìkò tirẹ̀

Ọgbọ́n l'ó ní àsìkò tirẹ̀

Rírúbọ l'ó ní àsìkò tirẹ̀ náà

Bẹ́ẹ̀ sì ni ríronú àti làákàyè ní àsìkò tìwọn.

 

Èyíkéyìí l'ó lè jẹ́ híhù ìwà rere. Àmọ́, nígbà tí ó yẹ nìkan l'ó lè jẹ́ bẹ́ẹ̀. Bí a bá ń ṣe nǹkan tí ìbá dára nígbà tí kò yẹ, á di ibi nìyẹn. Tí alẹ́ bá lẹ́ tán, a fi ọmọ ayò fún ayò. Tí a bá ń ṣe nǹkan l'ápọ̀jù, tí kìí ṣe ìwọ̀nba tí ó yẹ, á tètè di ìkà. Bí oore bá pọ̀ ní àpọ̀jù, á di ibi. Tótó ẹ̀yin àgbà, ó ṣe bíi òwe. 

b2ap3_thumbnail_Kasa.jpg

N kò gbà pé ríronú ni tòyìnbó àti àjẹmọ́-ẹ̀mí ni ti ènìyàn dúdú. »íṣe nǹkan tí ó yẹ ní àsìkò tí ó yẹ ni ti ènìyàn dúdú. Èrò pé tapá kan nìkanṣoṣo yìí wáyé nígbà tí àwọn Senghor, Cesaire àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ dá àbá pé "híhùwàdúdú" jẹ́ nǹkankínkan tí ó jẹ́ òdìkejì nǹkankínkan tí wọ́n wáá lè dá mọ̀ pé òyìnbó máa ń ṣe dáadáa. "Híhùwàdúdú" sì tún ni ohunkóhun tí àwọn òyìnbó fojú tẹ̀mbẹlu. Irú àwọn Senghor sọ bẹ́ẹ̀ nítorí pé ilé ìwé àwọn òyìnbó tí wọ́n rè kò jẹ́ kí wọ́n kọ́ nípa bí ìṣe àti ìwà Adúláwọ̀ ṣe rí gidi. 

N ò sì gbà pé ó yẹ kí a sọ pé nítorí ti Ifá ni àwọn òyìnbó ṣe iṣẹ́ burúkú wọn. N kò sì rò pé a ní láti ka ìṣe wọn sí ètò Atẹ́rẹrẹkáyé. Ní tèmi, bí ó ṣe yé mi ni pé, àwọn òyìnbó máa ń gbìyànjú láti da ètò náà rú kí iwin burúkú láti àwọn ilé òkúta jámànì tí wọ́n gbìyànjú láti sọ di òrìṣà ńláńlá tí wọ́n ń pè ní "God" lè fara rọ́pò Olódùmarè, kí ó lè jọba l'órí gbogbo ayé. Kí ó sì tún lè da ètò Olódùmarè rú. N kò gbà pé bákan náà ni wọ́n. Mo gbà pé ọ̀tá ara wọn ni wọ́n. 

Síbẹ̀síbẹ̀, tí ẹnìkan bá fẹ́ wánú Ifá láti rí ìdí tí àwọn òyìnbó fẹ́ ṣe nǹkan tí wọ́n máa ń ṣe, n kò lè dí wọn l'ọ́nà. Bí ẹnìkan fẹ́ wá ìtúmọ̀ nínú nǹkankínkan tí ó bá ń ṣẹlẹ̀ sí wọn kí nǹkan náà lè yé wọn, kí wọ́n sì tún lè ní àǹfààní láti pìwàdà fún ìlọsíwájú ìgbésí ayé wọn, n kò lè dí wọ́n lọ́wọ́. Irú ẹni bẹ́ẹ̀ kàn fẹ́ wá inú àṣà wa fún ìtúmọ̀ nǹkankínkan tí ó bá ń ṣẹlẹ̀. Gẹ́gẹ́ bíi ọ̀rọ̀ wọn ṣe yé mi sí, wọ́n sì fẹ́ kí nǹkankínkan tí ó sẹlẹ̀ yé wọn nítorí pé wọ́n gbà pé Olódùmarè wà ní ìdí ọ̀rọ̀ gbogbo tí ó ṣẹlẹ̀ nínú ayé.

A lè sọ pé, ní ìgbẹ̀hìn àwọn òyìnbó kò lè borí Olódùmarè bí wọ́n tilẹ̀ ń gbìyànjú láti ṣe bẹ́ẹ̀ tó. Síbẹ̀síbẹ̀, wọ́n ń gbìyànjú láti da ètò Olódùmarè rú. N kò gbà pé Olódùmarè rán wọn sílẹ̀ Adúláwọ̀, àti da ìdọ́gba ayé tí Olódùmarè fi dá ayé rú ni wọ́n fi ṣe bẹ́ẹ̀. Wọ́n lè ní ipò tàbí ìtúmọ̀ nínú ìgbésí ayé wa. Adánilóró fagbára kọ́ ni. Bí a tilẹ̀ lè kọ́ ọgbọ́n láti inú ìrírí ayé tí a gbà bí a ṣe ń wo ìhùwàsíni-òyìnbó tó, n kò gbà pé ìṣe òyìnbó jọmọ́ ìfẹ́ ọkàn Olódùmarè tàbí Ifá rárá. Mo gbà pé àti mú kí ìfẹ́ ọkàn Olódùmarè má ṣẹ ni ìdí tí wọ́n fi ń ṣe iṣẹ́ ibi wọn. Kí "God" wọn lè rọ Ọba Olódùmarè l'óyè, kí gbogbo ayé gbà pé asọdòrìṣà iwin olùtọ́jú-òyìnbó àti Elédùmarè jẹ́ bákan náà. Elédùmarè á fi wá ṣẹ́gun wọn, kí ìdọ́gba lè padà wáyé, kí òtítọ́, òdodo àti ìdájọ́ rere lè tún jọba nínú ayé. Àwa á ṣẹ́gun wọn l'ágbára Ọba Elédùmarè (Mo mọ̀ pé Ifá kò ṣe àṣìṣe, àmọ́, àwọn tí wọ́n ti ń gbìyànjú láti sọ ara wọn d'Òòṣàálá kí wọ́n lè fi amọ mọ ènìyàn kí wọ́n sì tún lè mí ẹ̀mí sínú wọn ni wọ́n máa ń ṣe èèṣì nígbà tí wọ́n ń gbìyànjú láti da ètò Ifá rú. Nígbà tí wọ́n ń sọ ara wọn di Olódùmarè).

b2ap3_thumbnail_Nsateaa.jpg

 

Tóò. Kí a padà sí ọ̀rọ̀ ìwà rere. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, n kò fún àwọn òyìnbó láàyè láti wà lára Ifá. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ bẹ́ẹ̀, kí a má ṣe gbàgbé ọ̀tá wa gidi. Èyí ni kòríkò tí ó mọ̀ọ́mọ̀ finúfẹ́dọ̀ purọ́ nípa ìwà kí ó lè fi àṣà wa mú wa sìn...kí a sì fún un l'áàyè láti ṣe bẹ́ẹ̀ tìrẹlẹ̀tìrẹlẹ̀. 

Nǹkan tí ó ń ṣẹlẹ̀ nínú ìbánisọ̀rọ̀ yìí ni ìdí pàtàkì tí kò yẹ kí òyìnbó wà nínú ẹ̀sìn wa. A máa ń bá ara wa jà nípa ipò wọn tàbí ìṣe wọn, tàbí ìtúmọ̀ wọn sí wa jù bí a ṣe ń rántí àwọn òyìnbó tí wọ́n ń gbìyànjú láti da tìwa rú. Ó tilẹ̀ lè jẹ́ pé bọ́yá kòríkò yẹn rò ó sínú pé, "Àwọn Adúláwọ̀ yóò bá ara wọn jà fún ìgbà pípẹ́ nítorí ti irọ́ yìí o!"

Mo ní ìretí pé, yàtọ̀ sí àwọn ọ̀dalẹ̀ gidi, kí ìjà jẹ́ ti ọ̀tá. N kò ì tíì rọ́dalẹ̀ ní ibi báyìí. Mo rí àwọn ènìyàn dúdú tí òye wọn yàtọ̀ sí ara wọn. Bí ó bá jẹ́ pé, mo rò pé èrò irú ẹni bẹ́ẹ̀ kò dára fún Adúláwọ̀, kí n sọ ojú abẹ́ níkòó l'ọ́nà tí ó yẹ oníwà-pẹ̀lẹ́. Nítorí pé ìwà-pẹ̀lẹ́ náà l'ó ní àsìkò tirẹ̀. Pàápàá jù lọ ní ìgbà tí a kò fẹnukò l'órí ọ̀rọ̀ kan láàrin àwa ènìyàn dúdú. Kí a yéé sọ̀rọ̀ nípa ẹnìkejì wa pé orúkọ wọn kò yẹ, tàbí oyè wọn kò yẹ. Bí a tilẹ̀ lè rò pé kò sọ́gbọ́n nínú nǹkan tí wọ́n ń sọ tó. K'á kàn sọ̀rọ̀ nípa èrò tí a rò pé kò bọ́gbọ́n mu láìtẹnu bọ ara wọn tàbí orúkọ wọn tàbí oyè wọn. Àwọn Yorùbá máa ń pa á l'ówe pé, "Ọgbọ́n ńbẹ nínú àgọ̀, àgọ̀ sì ńbẹ nínú ọgbọ́n." Bí a bá ń bá ara wa jà tí kìí ṣe ọ̀dalẹ̀ gidi, tàbí ọ̀tá gidi, bí a tilẹ̀ lè ṣọgbọ́n tó, àgọ̀ tí ó wà nínú rẹ̀ ni pé a ti ń gbin ohun-ọ̀gbìn ìjà láìfọwọ́ kan ẹni tí ó ti dìjà sílẹ̀ gan an. Nísìnyí, ìyẹn ni kòríkò. K'á má mú ohun ìjà olóró dání k'á kógun ba ẹni ti kò tilẹ̀ jẹ́ ọ̀tá gidi bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a lè rò pé wàhálà ńbẹ nínú èrò wọn. Títí dìgbà tí a ti rí i pé ọ̀dalẹ̀ ni, kí a fìwà-pẹ̀lẹ́ bá ara wa sọ̀rọ̀, k'á sì fi ìjà sílẹ̀ fún ẹlẹ́tàn àdìjàsílẹ̀. Àwọn Akan máa ń pa á l'ówe pé, "B¢koe din fata a, y¢hu no ¡ko ano, na ¢ny¢ fie." K'á má ṣe na ìyáńlá nítorí pé ó ń sọ nǹkan tí a rò pé kò dára. Tí ó bá ti burú tó k'á a sọ pé "N kò rò pé èrò yẹn dára fún ènìyàn dúdú." K'á má ṣe bú u tàbí fi láṣunpẹn sí i pé "báwo ni ó ṣe di ìyáńlá pẹ̀lú irú àgọ̀ bẹ́ẹ̀yẹn."

Nínú gbogbo ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, mo fẹ́ kí ó yé wa pé gbogbo nǹkan l'ó ní àsìkò tirẹ̀. Ìwà oníjà ní àsìkò tirẹ̀. Ìwà pẹ̀lẹ́ náà ni àsìkò tirẹ̀. Tí a bá ti l'ọ́gbọ́n tó láti mọ ìgbà tí ó yẹ kí a hùwà, èyíkéyìí lè di ìwà rere. Àmọ́, bí a kò bá ṣọ́ra, a máa rí ibi tí ìwà wa wà wá sí o. Kí ṣíṣe nǹkan tí ó yẹ nígbà tí ó yẹ jọba. Bẹ́ẹ̀yẹn ni a máa fi ìwà wa rere ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá àti ọ̀dalẹ̀ gidi. Àṣẹ.

b2ap3_thumbnail_Me2.jpg

Olùkọ́ Ọbádélé

 

Continue reading
1519 Hits
0 Comments

uMzantsi Akwantuo

uMzantsi Akwantuo

 

b2ap3_thumbnail_IMG_2419.jpg

Afei na masane aba Gaana afiri Umzantsi (Abibiman Anafoɔ). Nhyiamu a ɛfa Abibikasa nti na mekɔɔ hɔ no. Saa nhyiamu koraa no, ɛnhyɛ da nyɛ adeɛ kɛseɛ biara nanso, deɛ m'ani gyee ho ne sɛ menyaa kwan suaa isiZulu kasa kɔsi sɛ, afei, metumi bɔ nkɔmmɔ wɔ kasa no mu kakra. Nsɛmfua ne Kasamu a mesuaa no na ebi nie:

 

Sawubona (Wo ho yɛ?)

Yebo (Aane)

Kunjani? (Ɛte sɛn?)

Unjani wena/Wena unjani (Wo nso, wo ho te sɛn?)

Ngiyaphila (Me ho yɛ)

Nami ngiyaphila (Me nso, me ho yɛ)

Hamba kahle (Nante yie)

Hambani kahle (Monnante yie)

Sobonana (Yɛbɛhyia)

Ungasheshi, ngisisafunda isiZulu (Bɔkɔɔ, meda so resua Zulu kasa)

Uxolo, angikuzwa kahle (Mepa wo kyɛw, mente aseɛ yie)

Yini le ngesiZulu (Wei yɛ dɛn wɔ Zulu kasa mu?)

Uyasazi isiNgizi (Wotumi ka borɔfo?)

Angizwa (Mente aseɛ)

Ngiyabonga (Meda ase)

Uxolo (Mepa wo kyɛw)

Ngiyacela (Mepa wo kyɛw)

Ngiyafuna (Mepɛ...)

Angifuni (Mempɛ...)

Cha (Dabi)

Ngiyajabula ukukwazi (M'ani agye sɛ yɛahyia anaasɛ M'ani agye sɛ menim wo)

Ungubani igama lakho (Wo din de sɛn?)

Igama lami ngingu (Me din de...)

Ungubani isibongo sakho? (W'abusuadin de sɛn?)

Isibongo sami ngu (M'abusuadin de...)

Ngingu Ọbádélé (Meyɛ Ọbádélé)

Hlala phansi (Tena ase)

Uphumaphi? (Wofiri he?)

Ubuyaphi? (Wofiri he?)

Ngiphuma eGhana (Mefiri Gaana)

Amandla awetu (Tumi no yɛ yɛn dea)

Ayiko inkinga (Ɛnyɛ hwee)

Gologile (Yoo/bɔkɔɔ)

Uhlalaphi (Wote he?)

Ngihlala eAccra (Mete Nkran)

Ushadile (Woaware anaa?)

Yebo, ngishadile (Aane, maware)

Cha, angishadile (Dabi, menwareeɛ)

Ukhonze kumdeni wakho (Kyea w'abusuafoɔ ma me)

Umuhle namhlanje (Wo ho yɛ fɛ nnɛ)

Halala (Mo!)

Ngicela amanzi (Mepa wo kyɛw/mepɛ nsuo)

Ngifuna amanzi (Mepɛ nsuo)

Ngifuna uguhla (Mepɛ aduane)

Angifuna inyama (Mempɛ nam)

Iyimalini (Ɛyɛ ahe?)

Ngingakusiza (Metumi boa wo anaa?)

Unayo (Wowɔ...?)

Kumnandi (Ɛyɛ dɛ!)

Kuyashisa (Ahuhuro wɔ mu)

Kuyabanda (Awɔ wɔ mu)

Yisikathi sini (Abɔ sɛn?)

Ube nempelasonto emnandi! (Nnawɔtwe awieeɛ yi nyɛ wo anigyeɛ)

Qaphela (Hwɛ yie!)

Kwenzenjani? (Dɛn asɛm?/Ɛdeɛn na ɛreha wo?)

Ngihamba ikhaya (Merekɔ fie)

Sala kahle (Tena yie)

Salani kahle (Montena yie)

(U)Lala kahle (Da yie)

Kubi (bɔne)

Wamugelegile (Yɛnni aseda)

Kotwa (Nanso)

Namhlanje (Nnɛ)

Manje (Seesei ara)

Kunye (Baako)

Isibili (Mmienu)

Kuthathu (Mmiɛnsa)

Okune (Ɛnan)

Isihlanu (Enum)

Isithupha (Nsia)

iSonto (Kwasiada)

uMsombuluko (Dwoada)

uLwesibili (Benada)

uLwesithathu (Wukuada)

uLwesine (Yawoada)

uLwesihlanu (Fiada)

uMgqibelo (Memeneda)

Sivuliwe (Bue)

Sivaliwe (To mu)

Mfowethu (Nuabarima)

Tate (Nuabaa)

 

 

Mesuaa nsɛmfua afoforɔ nso kaa ho nti sɛ mekae a, mɛtwerɔ wɔ ha atoa so. Meduruu uMzantsi Benada anɔpa na Benada anwummerɛ no, sɛnea na mereka isiZulu no, nkurɔfoɔ no angye anni sɛ meduruu hɔ saa da no. Afei, wɔannye anni sɛ mankɔ hɔ da. Na ɛyɛ me sere. Mehyiaa nnamfoɔ te sɛ Neo a ɔyɛ Zuluni nanso ne din yɛ Sotho din. Mesane hyiaa Thando, Dineo, Awerekyekye, Thandi, ne wɔn a ɛkeka ho pii. 

b2ap3_thumbnail_IMG_2412.jpg

Na sɛdeɛ mekaeɛ no, nhyiamu a ɛfa kasa ho nti na mekɔɔ hɔ. Adwumakuo a ɛhyehyɛɛ saa nhyiamu no, yɛfrɛ no Amabhubesi a saa din no kyerɛ "gyata" wɔ Zulu kasa mu. Sɛbe, wɔanhyehyɛ nhyiamu no yie. Berɛ a meduruu hɔ no na anka ɛwɔ sɛ wɔfa me wɔ wiem hyɛn gyinabea. Metwɛnn wɔn saa ara no, nanso wɔamma da! Baabi a mesoɛeɛ no (a yɛfrɛ hɔ Zulu Nyala) na wɔsomaa hyɛnkani sɛ ɔmmra mmɛfa me. Ɔno na yɛfrɛ no Neo a mekaa ne ho asɛm wɔ soro hɔ no. Da a anka nhyiamu no bɛhyɛɛ aseɛ no, na anka ɛwɔ sɛ wɔfa me firi Zulu Nyala hɔ no nso nanso, tweaa! Wɔamma da! Nti metuaa hyɛnkani foforɔ (Awerekyekye) sɛ ɔmfa menkɔ. Wɔn a na wɔkasa wɔ hɔ nso, ebinom wɔ nimdeɛ a ɛfa Abibikasa ho nsɛm nanso, ebinom nso na wɔnnim hwee. Wei nyinaa nti na mebɔɔ me tirim pɔ sɛ Amabhubesifoɔ no, wɔn mfasoɔ nko ara na na woredwene. Ɛnyɛ adesua ne adekyerɛ ne nimdeɛ ho dɔ nti na wɔtoo nsa frɛɛ yɛn nyinaa sɛ yɛmmra. Ɛno nti, sɛ saa nhyiamu sane ba so bio afe a ɛreba yi deɛ, mennye nni sɛ mɛkɔ. 

 

Nanso, yei nyinaa nkamfua no, m'ani gyee me isiZulu adesua pii na m'ani da so sɛ mɛnya kwan asane akɔ uMzantsi bio.

Continue reading
2743 Hits
0 Comments

Iṣẹ́ pọ̀

Iṣẹ́ pọ̀

L'ójoojúmọ́ mo rí pé iṣẹ́ pọ̀ fún àwa ènìyàn dúdú, t'ó sì pọ̀ fún èmi pàápàá. K'á má ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́ àtigbowó. Iṣẹ́ t'ó ṣe pàtàkì jù lọ ni iṣẹ́ t'ó jẹmọ́ àyànmọ́ mi. Mo rí pé a nílò gbogbo àwọn iṣẹ́ tí mo máa mú wá. Mo sì rí pé títí dìgbà tí mo wáá mú un jáde, àwọn afọ́jú tí wọ́n ò mọ nǹkan tí wọ́n ń sọ máa ta iṣẹ́ èdè l'ábùkù. Wàhálà kan tí mo rí ni pé nígbà mìíràn mo máa ń bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ láìparí. Èmi dẹ̀ mọ̀ wí pé irú ìwà bẹ́ẹ̀yẹn ò níí ràn mí l'ọ́wọ́ rárá. 'Torí náà, mo gbọ́dọ̀ mójútó àwọn nǹkan tí mo ní láti ṣe. 

Èròǹgbà tèmi sì gbọ́dọ̀ jẹ́ àtimá ṣe ààbọ̀ṣe nígbésí ayé mi. K'á ṣe é. K'á parí. K'á parí rẹ̀ l'ọ́nà t'ó yẹ t'ó sì péyẹ l'ó gbé 'ni l'áruge. Ìyẹn náà niyì òṣìṣẹ́. Àṣeyọrí ń bẹ̀ níwájú wa. Ọwọ́ wa á tẹ̀ ẹ́ b'ó bá yá. Àṣẹ.

Continue reading
1391 Hits
0 Comments

Adekyerɛ wɔ Gaana Suapɔn wɔ Legon

Adekyerɛ wɔ Gaana Suapɔn wɔ Legon

b2ap3_thumbnail_ok_logo.png 

Obi nnim adekyee-mu-nsɛm

 

Continue reading
2285 Hits
Offers and bonuses by SkyBet at BettingY com